Acts 5:12

Àwọn aposteli wo ọ̀pọ̀ sàn

12A sì ti ọwọ́ àwọn aposteli ṣe iṣẹ́ ààmì àti iṣẹ́ ìyanu púpọ̀ láàrín àwọn ènìyàn. Gbogbo wọn sì fi ọkàn kan wà ní ìloro Solomoni.
Copyright information for YorBMYO